Iyawo pasitọ Enoch Adeboye, Foluke Adeboye ti sapajuwe ọkọ rẹ gẹgẹ bi ọkunrin akinkanju ti gbogbo obinrin fẹran lati fi ṣe ọkọ. Foluke Adeboye sọ bẹẹ ni oju ọpọ ikansiraẹni Twitter rẹ lasiko ti wọn ṣe ...
Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ okunrin kan ati iya rẹ lori ẹsun pe awọn mejeji pa aburo rẹ lọna ati fi ṣoogun owo. Okunrin ọhun, Afeez Olalere jẹwọ fun ikọ akọṣẹmọṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko pe iya oun ...
Some results have been hidden because they may be inaccessible to you
Show inaccessible results